E n'le n 'be un o. A ku ipade Satide! Was that not another fine Yodaai get together?
If you missed our October gathering, not to worry! A full recap is on the way in our Yodaai news letter. In the meantime, here are some photos from the meeting.
|
There was a lot of love and affection in the air... |
|
New faces, Mr and Mrs Lawal. E kaa bo so'ri eto yi o! |
|
Dr Badewa, Board member |
|
Dr Ogunbi, l'ati isale Eko |
|
Awon alagba wa n'ko m'ole pelu onilu wa...! |
|
Yodaai President, Dr Adediji & Mr Latunde Addey |
|
A scavenger hunt - those kids actually had to read & follow instructions... |
|
More love... |
|
Left to Right - Mr Sholanke and son, Mr Babatunde |
|
L to r Dr Sesi Ogunbi, Mrs Adagunodo and the Secretary of Faaji, Mrs Abolade... |
|
Awon omo Babatunde, omo Odeleye, omo Badewa, Omo Fadamiro, ati omo Adediji |
|
Our Onilu surprise, Mr Sholanke, the senior and Mr Sholanke, the son. |
|
Surprise! |
|
Mr Okeowo ati Akowe imowe, secretary of education committee, Mrs Popoola. |
|
Mrs Babatunde, (Thanks for the catering asistance)-, Dr Sesi Ogunbi, fine collector, Mrs Adagunodo |
|
Mrs Adediji, (thanks for the catering assistance) and Mrs Abolade, Secretary of Faaji. |
|
See the "
comments" or "
Post a comment" section in green down here at the end of the post? Go on! Click on it and see what happens. Join the community. Leave a comment! You can be anonymous too. Just say something to be an active participant.
Funke Abolade.
Social/Publicity Secretary
Eku ise faaji,igbalejo na leku koda o ti lewaju. Thanks to all that attended the meeting it was awesome. Ipade wa bi oyin o.
ReplyDeleteLaitan Adediji.
E se e ku idide. E ku a'no wo si. Bayi bayi la o maa ri o. I had a fantastic time. Can't wait till ajodun...
ReplyDeleteE ku alejo wa ana. E si ku ise takuntakun ti e nse. Ajinde ara yio ma je o.
ReplyDeleteAwon aworan ipade ati akole won rewa pupo, e se gan an ni.
Ipejopo wa Ko ni baje o, Aamin.
Ayodele Babatunde.
Eyi wa, l'eni ko si nkan; Is Gaju !!!
ReplyDeleteOlabisi Babatunde.
Is gaju gan ni o! E kaa bo s'ori eto yi. E ku wahala mi ana o. I hope Jibola had fun!
ReplyDeleteE ku alejo ana o , asi ku ipade naa . Faaji naa ga gidi o koda awon omo paapa gbadun re gidi o .E se a dupe o .Ipade wa bi oyin o .
ReplyDeleteBisi Badewa
Akowe onifaaji, eyin ome egbe wa . Eku ise . Eku eto Egbe . Ajo se yoo gbe wa o . Esi ku alejo wa . Asodun modu ni se awo asodun modun , ase osu mosu ni se awo asosu mosu. A o tun se eyi to ju bee lo . Ire owo, ire omo ire aiku baale oro ni yo ma ba gbogbo wa O .Ase ! Eledumare.
ReplyDeleteE ku alejo o, E si ku inawo. I waju lopa ebiti nresi, iwaju lao ma lo o, ase. It was a wonderful gathering indeed!
ReplyDeleteAbiodun Badewa
E se o. Dr Badewa. I had a blast and I'm glad everyone seemed to have had a fun time too. Adura mi ni pe ki a ma je ki o su gbogbo wa o. Amin. We need to keep the enthusiasm going and from strength to strength...
ReplyDeleteDoyin and I had a wonderful time at the "ipade" yesterday. It was a good time of fellowship. Let's make sure we pass our rich culture onto our children. Sesi Dosunmu-Ogunbi
ReplyDeleteOctober 16, 2011 4:37 PM
cut and pasted by the blog editor to this post.
Mo ki gbogbo egbe o lati idile Lawal. Ese eku alajo wa. Oluwa a wa pelu wa ajose wa koni baje o amin. Our special thanks to all the members for the warm welcome, we had a good time, and may God bless you all. Long live YODAAI !!
ReplyDeleteToyin Lawal
You are most welcomed!
ReplyDeleteAnother great and fun meeting! Thanks to the Abolades for the hospitality.
ReplyDelete