Monday, February 11, 2013

An ode to love...

A Serenade in Yoruba 

Wi fun mi, Olufe mi,
Iwo eni ti okan mi fe,
Fi ona ife re han mi,
Ki emi ma d'abi alaare,
 Ti o n s'ina kaa kiri,
Bi agbo ti o so nu,

Ereke re wu mi,
Orun re si dun wo pelu ileke,
Fi akara didun da mi duro,
Fi eso igi tu mi ninu,
Nitori aisan ife n'se mi.

Dide olufe mi,
Arewa mi kan na a,
Ki o si ja de, ka lo,
Adaba mi, je ki emi o ri oju re,
Nitori oju re si lewa,
Je ki emi gbo ohun re,
Ni tori didun ni ohun re.
Aisan ife nse mi, olufe mi,
Iwo eni ti okan mi fe.

Adapted from & inspired by the Songs of Solomon...
Happy upcoming Valentine's day,
to all great Yodaaites!

Translate single lines to English if you dare, below in the comments section...




F. A.

5 comments:

  1. Woo, eleyi po o. Dr Abolade nibo le ti n ri awon ewi yi. This is great I have to visit Naiga to be able to translate this o. Thank you so much. Ko ni tan nibe o.

    ReplyDelete
  2. First line- Tell me my love

    Rakiya Adediji

    ReplyDelete
  3. 2nd line

    You whom my heart desires...

    ReplyDelete
  4. here goes 3rd, 4th , 5th & 6th line.
    "Show me the way to your love
    That my heart would not be weary
    Lost and wandering
    Like a missing ram".

    ReplyDelete
  5. Wow thank you for those lines. I' m working on some of the rest.

    ReplyDelete

Go on - Leave a message!